Open Studio
MP3

Free to use on YouTube, TikTok, Reels — no Content ID claims. Tag @starsinger.ai when you do.

ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026

Creator
@clever_cowbell_60
Afrobeats2:35October 1, 2026
0:00 2:35

Lyrics

[Chorus]
Ope lo ye Olorun, Baba wa
Odun metadinlogun la fi yin O
Sainte Thérèse, gbadura fun wa
Saint Augustin, gbadura fun wa
Egbe Yoruba Saint Augustin, a dupe!

[Verse 1]
Augustin Mimọ, olukọ wa
Iwọ ti ri imọlẹ otitọ
Kọ wa bi a ti le kọrin si Ọlọrun
Ki a le sin O pẹlu ayọ

[Verse 2]
Therese Mimọ ọmọde Jesu
Iwọ ti o n ta ododo ifẹ
Pa ododo ifẹ rẹ sori wa
Ki ifẹ Ọlọrun gbe inu wa

[Verse 3]
Lati ọdun 2009 titi di oni
Ọwọ Oluwa ti wa pelu wa
Awọn ti o ti sun, Baba dariji wọn
Awọn ti o wa laaye, Baba busi wọn

Refrain (fin):
Ope lo ye Olorun, Baba wa
Odun metadinlogun la fi yin O
Sainte Thérèse, gbadura fun wa
Saint Augustin, gbadura fun wa

Iyin, Ọla, Ogo ni fun Baba, fun Ọmọ, fun Ẹmi Mimọ!
Amin!

Want to make Afrobeats yourself? See how Star Singer compares to Suno and Udio for AI Afrobeats generation.

Make a Afrobeats like this with AI

Generate your own AI Afrobeats song in 90 seconds — first one free, full commercial rights, vertical music video included.

Make an AI Afrobeats song → Open Studio

FAQ

Who made "ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026"?

"ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026" was made by @clever_cowbell_60 on Star Singer, where anyone can write and sing an original song with AI.

What genre is ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026?

ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026 is Afrobeats.

Can I listen to "ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026" for free?

Yes. "ORIN 17ÈME ANNIVERSAIRE - EGBE YORUBA SAINT AUGUSTIN OPE WA FUN OLODUMARE - 1er Octobre 2026" streams free on Star Singer — no subscription required. You can also make your own: one AI song a day is free, extra songs with a lyric video are $1.99, a lip-synced music video starring you is $19.99, and cinematic videos start at $2.99.

Can I create my own AI song?

Yes. Star Singer lets you create AI-generated songs and music videos. Clone your voice, pick any style, and generate original music. Listening is free and unlimited, and one song a day is free to make — no subscription.

Make an AI Afrobeats song →